The clock is ticking Yoruba

AGOGO NKA’JO WA WA!

AKOKO NSARE LO TETE!

Ibapade re pelu Olorun sunmole …

Bibeli wipe: “Mura lati pade Ọlọrun rẹ!” Amosi 4:12.

Nje O nmurasile? Nje O Setan?

“Awa o ti ṣe là a, bi awa kò ba nani irú igbala nla bi eyi?” Heberu 2:3

O ni akoko kan ti o ti da pelu iku ati Olorun!

Niwọn bi a si ti fi lelẹ fun gbogbo enia lati kú lẹ̃kanṣoṣo, ṣugbọn lẹhin eyi idajọ.” Heberu 9:27

Olorun nfe ki o murasile!

Kini ki emi ki o se?

1. Mo wipe elese ni o
“Gbogbo enia li o sá ti ṣẹ̀, ti nwọn si kuna ogo Ọlọrun” Romu3:23
2. Mo wipe orun-apadi ni ijiya fun ese
“Ori awọn enia buburu li a o dà si ọrun apadi, ati gbogbo orilẹ-ède ti o gbagbe Ọlọrun” Orin Dafidi 9:17.
3. Mo wipe o ko gba ara re la nipa agbara ara re
“Gbogbo ododo wa si dabi akisa ẹlẹgbin” Isaiah 64:6
4. Ronupiwada ki o si gboran si Olorun
“Pẹlupẹlu igba aimọ̀ yi li Ọlọrun ti foju fò da; ṣugbọn nisisiyi o paṣẹ fun gbogbo enia nibi gbogbo lati ronupiwada” Ise 17:30
5. Gba Jesu Kristi Gbo gegebi Olugbala re.
“Nitori Ọlọrun fẹ araiye tobẹ̃ gẹ, ti o fi Ọmọ bíbi rẹ̀ kanṣoṣo funni, ki ẹnikẹni ti o ba gbà a gbọ́ má bà ṣegbé, ṣugbọn ki o le ni ìye ainipẹkun” Johannu 3:16
6. Jewo awon ese re fun Jesu
“Bi awa ba jẹwọ ẹ̀ṣẹ wa, olõtọ ati olododo li on lati dari ẹṣẹ wa jì wa, ati lati wẹ̀ wa nù kuro ninu aiṣododo gbogbo” 1 Johannu 1:9
7. Gbe Igbe-Aye Ihinrere
“Ṣugbọn ki ẹ jẹ oluṣe ọ̀rọ na, ki o má si ṣe olugbọ́ nikan, ki ẹ mã tàn ara nyin jẹ” Jakobu 1 :22

Fun alaye kikun kan si: contact@sweethourofprayer.net

You can find equivalent English tract @

The clock is ticking