Do you know Yoruba12 

 

Wipe elese ni o Niwaju Olorun?

“Gbogbo eniyan ni o sa ti se, ti won si kuna ogo Olorun” Rom.3:23

“Bi awa ba wipe awa ko ni ese. awa tan ara wa je, otito kan ko si si ninu wa” 1Johannu 1:8

Wipe iwo ni adehun ipade pelu iku ati pelu Olorun!

“Niwon bi a si ti fi lele fun gbogbo eniyan lati ku leekansoso, sugbon leyin eyi idajo.” Heberu 9:27

Wipe Olorun yio se idajo re?

Ori awon eniyan buburu ni a o da si orun apadi, ati gbogbo orile-ede ti o gbagbe Olorun” Orin Dafidi 9:17

“Yio si so won sinu ina ileru: nibe ni ekun oun ipayinkeke yio gbe wa” Mattiu 13:42

Ona kan wa ti o fi lee mu ona aye re to pelu Olorun. 

“Nitori Olorun fe araye tobee ge, ti O fi Omo bibi re kansoso funni, ki enikeni ti o ba gba A gbo ma ba segbe, sugbon ki o le ni iye ainipekun.” Johannu 3:1

Kinni mo le se lati ni iye ainipekun?

 

  1. Ronupiwada

“Pelupelu igba aimo yi ni Olorun ti gboju fo da; sugbon nisisiyi o pase fun gbogbo eniyan nibi gbogbo lati ronupiwada. Ise 17:30

  1. Gba Jesu Kristi gegebi Olugbala re

Sugbon iye awon gba A, awon ni o fi agbara fun lati di omo Olorun, ani awon na ti o gba oruko re gbo” Johannu1:12

  1. Jewo ese re fun Olorun

“Bi awa ba jewo ese wa, olooto ati olododo ni Oun lati dari ese wa ji wa, ati lati we wa nu kuro ninu aisododo gbogbo” 1Johannu 1:9

  1. Gbe igbe-aye ihinrere

“ Sugbo ki e je oluse oro na, ki o ma si se olugbo nikan, ki e maa tan ara yin je” Jakobu 1:22

“ Pa ofin mi mo, ki iwo ki o si ye; ati ase mi bi omoloju re” Owe7:2

 

You can find equivalent English tract @

Do you know?